Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
0% found this document useful (0 votes)
9 views1 page

HYMNS

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1/ 1

JESUS DISCIPLES GOSPEL MINISTRY

EASTER HYMNS
Hymn 502. Hymn 494

Osi fi ejere wewa nu kuro ninu ese wa gbogbo. Eje jesu Kristi ninwe wa mo kuro ninu ese

Ifihan 1:5. wa gbogbo 1johannu 1:7

1. Otito jesu lo fun wenumo bi? 1. Kilo le wese minu

A we o ninu eje odo aguntan. Kosi lehin eje jesu

Iwo ha gbekele ore ofe re. Kilo tun le who mi san

A we o ninu eje odo aguntan. Kosi lehin eje jesu

Chorus-- A we o ninu eje chorus--- ah! Eje yebiye

ninu eje odo aguntan fun Okan. To mumi fun bi sno

Aso re ha fun fun o si mo laulau. Ko si sun Miran mo

A we o ninu eje odo aguntan. Kosi lehin eje jesu

2. Onba olugbala rin lojojumo? 2. Fun wenumo mi nko ri

A we o ninu eje odo aguntan. 'kan mi lehin lehin eje jesu

O ha gbekele eni ta kan mogi. Ohun ti mo gbekele

A we o ninu eje odo aguntan. Fun dariji leje jesu

3. Aso re ha mo lati pade jesu? 3. Etutu fun ese kosi

A fomo ninu eje odo aguntan. Kosi lehin eje jesu

Okan re ha mo lati pade jesu? Ise rere kan kosi

Kawe o ninu eje odo aguntan. Kosi lehin eje jesu

4. Bo ewu eri ese si apakan 4. Gbogbo ignekele mi

Kawe o ninu eje odo aguntan. Ireti mi leje jesu

Isun kan tonsan fun gbogbo Okan aimo gbogbo ododo mi ni

Jo lo we ninu eje odo aguntan. Eje kiki eje jesu.

You might also like