A Nasty Boy
A Nasty Boy A Nasty Boy jẹ́ ìwé ìròyìn àkọ́kọ́ kan tí wọ́n da sílẹ̀ ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kejì ọdún 2017, tí ó da lè ọ̀tọ̀ nípa àwọn LGBTQ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìwé yí ni ó ń sọ nípa ìtàn, ìrírí ati àkòrí ọ̀rọ̀ nípa bí àwùjọ oríṣiríṣi ní orílẹ̀-èdè agbáyé ṣe ń dẹ́yẹ sí àwọn LGBTQ, pẹ̀lú bí àwọn orílẹ̀-èdè míràn ṣe fòfin dè wọ́n.Ìwé ìròyìn A Nasty Boy ni ọgbàẹ́ni Richard Akuson tí ó jẹ́ agbẹjọ́rò, oníṣẹ́ ìròyìn tí ó jọ mọ́ oge, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ní inú oṣù kẹfà ọdún 2017, wọ́n ṣe àfihàn àpilẹ̀kọ A Nasty Boy nínú CNN article[1] fún ayé rí. Lẹ́yìn èyí, Soon, Dazed declared[2] ìwé ìròyìn náà di gbajú-gbajà láàrín àwọn ìwé ìròyìn àtìgbà-dégbà tí ó da lè orí Vogue[3] Oríṣiríṣi àwọn olóòtú ni wọ́n fi A Nasty Boy sí ara àwọn àkòjọ ìwé tíbwọ́n pè ní What to Read this Fall , látàrí èyí, ìwé ìròyìn yí ti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tí wọ́n ka ìwé wọn lórí The Guardian,[4] BBC,[5] The Observer,[6] The Economist, i-D,[7] OkayAfrica, Mic,[8] àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn iṣẹ́ àkànṣe wọn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Championing Diversity
Ní ọdún 2017, A Nasty Boy pẹ́lú WeTransfer àti creative network, ṣe agbékalẹ̀ The Dots láti ṣe awárí ẹ̀bùn ọpọlọ àwọn LGBTQ lágbàáyé.
Nasty 40 List
Ní ọdún 2018, A Nasty Boy's inaugural list,[9] àtẹ̀jáde ọdún náà ṣe àgbéjáde àwọn ẹlẹ́bùn ọpọplọ ogójí tí wọ́n lòdì sí ìgbésẹ̀ àwọn LGBTQ nípa lílo àwòrán yíyà, àpilẹ̀kọ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Lára àwọn tí wọ́n wà ní orí àtòjọ wọn ni Ruth Ossai, Adebayo Oke Lawal, Papa Oppong, Yagazie Emezi, àti Rich Mnisi.
New Leadership
Ní inú oṣù kíní ọdún 2020, olùdásílẹ̀ ìwé náà Richard Akuson fi léde wípé ìwé ìròyìn náà ni Vincent Desmond ẹni tí ó jẹ́ oníṣẹ́ẹ́ ìròyìn tí ó gba amì-ẹ̀yẹ yóò jẹ́ olóòtú àgbà tuntun fún ìwé náà.[10]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Idowu, Torera. "Is this Nigeria's most controversial magazine?". CNN. Retrieved 2019-09-17.
- ↑ Dazed (2017-06-29). "Get to know Nigeria's most controversial fashion magazine". Dazed (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-17.
- ↑ "What Vogue Editors Will Be Reading This Fall". Vogue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-18.
- ↑ Akinwotu, Emmanuel (16 November 2017). "Nigeria's Nasty Boy: 'People in my law class thought I worked for a porn site'". The Guardian. Retrieved 17 September 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "The male models wearing dresses in Nigeria". BBC News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-17.
- ↑ "The new magazine in Nigeria daring to subvert gender norms". The France 24 Observers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-18.
- ↑ Wheeler, André-Naquian (August 1, 2017). "'a nasty boy' magazine is challenging what masculinity means in nigeria". i-D. Retrieved September 17, 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "This Nigerian fashion magazine is dedicated to dismantling gender stereotypes". Mic (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-09-18.
- ↑ "A Nasty Boy Magazine's 'Creative Class of 2018' Highlights 40 African Creatives Who Are Disrupting the Status Quo". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-10-16. Retrieved 2019-09-18.
- ↑ "A Nasty Boy Founder Richard Akuson Announces Vincent Desmond as New Editor & Publisher | Exclusive & Interview". Brittle Paper. 2020-01-02. Retrieved 2020-07-07.