Chaka Khan
Ìrísí
Chaka Khan | |
---|---|
Khan performing at the Chumash Casino Resort in Santa Ynez, California. | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Yvette Marie Stevens |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Chaka Adunne Aduffe Hodarhi Karifi Khan |
Ìbẹ̀rẹ̀ | North Chicago, Illinois, United States |
Irú orin | R&B, jazz, funk, soul, disco, adult contemporary |
Occupation(s) | Singer, songwriter |
Years active | 1973–present |
Labels | ABC (1972–1978) Warner Bros. (1978–1998) MCA (1979-1982) NPG Records (1998-2001) Burgundy (2005-present) |
Associated acts | Rufus, Prince |
Website | ChakaKhan.com |
Chaka Khan (oruko abiso Yvette Marie Stevens; ojoibi March 23, 1953) je akorin-olorin ara Amerika to gbajumo ni ewadun 1970 gegebi asiwaju fun egbe olorin to unko orin funk Rufus. Diedie Khan bere si ni da korin latin 1978. Ninu awon orin re togbajumo, to dako tabi pelu Rufus, ni "Tell Me Something Good", "Sweet Thing", "Ain't Nobody", "I'm Every Woman", "I Feel for You" ati "Through the Fire".
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |