Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Dinara Safina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Dinara Safina
Динара Сафина
Orílẹ̀-èdèRọ́síà Rọ́síà
IbùgbéMonte Carlo, Monaco
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kẹrin 1986 (1986-04-27) (ọmọ ọdún 38)
Moscow, Soviet Union
Ìga1.82 m (5 ft 11+12 in)[1]
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2000
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owóUS10,585,640
Ẹnìkan
Iye ìdíje360–173 (67.54%)
Iye ife-ẹ̀yẹ12 WTA, 4 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (April 20, 2009)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàF (2009)
Open FránsìF (2008, 2009)
WimbledonSF (2009)
Open Amẹ́ríkàSF (2008)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTARR (2008, 2009)
Ìdíje Òlímpíkì Silver medal (2008)
Ẹniméjì
Iye ìdíje181–91
Iye ife-ẹ̀yẹ9 WTA, 3 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 8 (May 12, 2008)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàQF (2004, 2005)
Open Fránsì3R (2006, 2007, 2008)
Wimbledon3R (2005, 2008)
Open Amẹ́ríkàW (2007)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje ÒlímpíkìQF (2008)
Last updated on: October 10, 2011.

Dinara Mikhailovna Safina (Rọ́síà: Динара Михайловна Сафина, Àdàkọ:Lang-tt), ojoibi April 27, 1986 ni Moscow, je agba tenis ara Rosia lati eya Tatari. Safina de ifunnipo No. 1 Lagbaye bi enikan.

Safina gba ipo keji ninu awon idije Grand Slam enikan ni 2008 French Open, 2009 Australian Open, ati 2009 French Open, nibi to ti kuna lowo Ana Ivanovic, Serena Williams, ati Svetlana Kuznetsova, ni telentele.


  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named WTA_Stats