Hiroshima
Ìrísí
Hiroshima 広島 | ||
---|---|---|
広島市 · Hiroshima City | ||
Atomic Bomb Dome (left) and modern buildings | ||
| ||
Location of Hiroshima in Hiroshima Prefecture | ||
Country | Japan | |
Region | Chūgoku, Sanyō | |
Prefecture | Hiroshima | |
Government | ||
• Mayor | Tadatoshi Akiba (SDP) | |
Area | ||
• Total | 905.01 km2 (349.43 sq mi) | |
Population (January 2010) | ||
• Total | 1,173,980 | |
• Density | 1,297.2/km2 (3,360/sq mi) | |
Time zone | UTC+9 (Japan Standard Time) | |
- Tree | Camphor Laurel | |
- Flower | Oleander | |
Phone number | 082-245-2111 | |
Address | Hiroshima-shi, Naka-ku, Kokutaiji 1-6-34 730-8586 | |
Website | Hiroshima City |
Hiroshima (広島市 Hiroshima-shi ) ( listen (ìrànwọ́·ìkéde)) jẹ́ ìlú ní orílẹ̀ èdè Japan àti olúìlú Ìbílẹ̀ Hiroshima, ó sì tún jẹ́ ìlú tótóbijùlo ní agbègbè Chūgoku ní apáìwọ̀ọ̀rùn Honshū, tó jẹ́ erékùṣù títóbijùlọ ní Japan. Ó jẹ́ ìlú àkọ́kọ́ nínú ìtàn tó jẹ́ piparun pẹ̀lù bọmbù átọ́mù nígbà tí orílẹ̀ èdè Améríkà jù síbẹ̀ ní ago 8:15 am ọjọ kẹfà Oṣù kẹjọ Ọdún 1945, ní súnmọ́ òpin Ogun Àgbáyé Kejì.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Hakim, Joy (1995). A History of Us: War, Peace and all that Jazz. New York: Oxford University Press. ISBN 0-19-509514-6.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |