Jean-Claude Duvalier
Ìrísí
Jean-Claude Duvalier | |
---|---|
33rd President of Haiti | |
In office April 22, 1971 – February 7, 1986 | |
Asíwájú | François Duvalier |
Arọ́pò | Henri Namphy |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Keje 1951 Port-au-Prince, Haiti |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Haitian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Michèle Bennett (married 1980-1990) |
Domestic partner | Veronique Roy (?-present) |
Ẹbí | Francois Duvalier (father, deceased) Simone Duvalier (mother, deceased) |
Àwọn ọmọ | François Nicolas Duvalier Anya Duvalier |
Jean-Claude Duvalier, pipe bi "Bébé Doc" tabi "Baby Doc" (ojoibi July 3, 1951) lo je Aare ile Haiti lati 1971 titi di igba ti won fi tipatipa lekuro ni 1986 leyin igberadide ilu to sele. O ropo baba re, François "Papa Doc" Duvalier, gegebi olori Haiti nigba ti baba re ku ni 1971.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |