Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Julio Cortázar

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Julio Florencio Cortázar
Pen nameJulio Denis (in his first two books)
Iṣẹ́Writer, Translator, Novelist
GenreNovel, story, poetry, prose poem, short story
Literary movementMagic realism
Notable worksHopscotch

Julio Cortázar, oruko abiso Jules Florencio Cortázar, (August 26, 1914 – February 12, 1984) je olukowe ati akoewi ara Argentina (lopo ni ibere aye re) sugbon o gbajumo gege bi oluda awon itan soki. O ni ipa lori opo awon olukowe ni Amerika Latin lati Mexico de Argentina. Opo ninu awon ise e o se won ni France, nibi to lo ungbe lati 1951.