Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Maurice Wilkins

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Maurice Wilkins
Maurice Wilkins
Ìbí(1916-12-15)15 Oṣù Kejìlá 1916
Pongaroa, Wairarapa,
New Zealand
Aláìsí5 October 2004(2004-10-05) (ọmọ ọdún 87)
Blackheath, London,
United Kingdom
PápáPhysics, Molecular biology
Ilé-ẹ̀kọ́University of California, Berkeley
Ó gbajúmọ̀ fúnX-ray diffraction, DNA
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physiology or Medicine (1962)

Maurice Hugh Frederick Wilkins CBE FRS (15 December 1916 – 5 October 2004) je omo New Zealand ara Ilegeesi asefisiksi ati asebioloji onihoro, ati elebun Nobel ti iwadi re ko ipa lori oye sayensi ita yanyan, iyasoto isotopu, iwokekere oloju ati X-ray diffraction, ati si idagbasoke radar. O gbajumo fun ise re ni King's College London lori igbamu DNA. Fun ise yi, ohun, Francis Crick ati James Watson gba Ebun Nobel fun Iwosan 1962, "fun iwari nipa igbamu onihoro awon onikikan nukleiki ati pataki re igberin ifitonileti ninu awon eroja alaaye."[1]


  1. The Nobel Prize in Physiology or Medicine 1962. Nobel Prize Site for Nobel Prize in Physiology or Medicine 1962.