Octave Mirbeau
Ìrísí
Octave Mirbeau | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | Trévières, France | 16 Oṣù Kejì 1848
Ọjọ́ aláìsí | 16 February 1917 Paris, France | (ọmọ ọdún 69)
Iṣẹ́ | Novelist, Playwright |
Notable works | Le Journal d'une femme de chambre (1900) Les affaires sont les affaires (1903) |
Octave Mirbeau (February 16, 1848 in Trévières, Calvados - February 16, 1917) je ara Fransi oniroyin, alagbewo iseona, olukowe irinajo, oniweroyin, onitan-enu, ati akoere oriitage. Ninu awon iwe re niwonyi : Le Calvaire (1886), L'Abbé Jules (1888), Sébastien Roch (1890), Le Jardin des supplices (1899), Le Journal d'une femme de chambre (1900), Les affaires sont les affaires (1903), La 628-E8 (1907), Le Foyer (1908), Dingo (1913).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |