Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Srinivasa Ramanujan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Srinivasa Ramanujan
Ìbí(1887-12-22)22 Oṣù Kejìlá 1887
Erode, British India
Aláìsí26 April 1920(1920-04-26) (ọmọ ọdún 32)
Chetput, (Madras), British India
IbùgbéTamil Nadu, India
Ọmọ orílẹ̀-èdèIndian
PápáMathematics
Ibi ẹ̀kọ́Government Arts College
Pachaiyappa's College
Cambridge University
Academic advisorsG. H. Hardy
J. E. Littlewood
Ó gbajúmọ̀ fúnLandau–Ramanujan constant
Mock theta functions
Ramanujan conjecture
Ramanujan prime
Ramanujan–Soldner constant
Ramanujan theta function
Ramanujan's sum
Rogers–Ramanujan identities

Srīnivāsa Aiyangār Rāmānujam FRS, daada bi Srinivasa Iyengar Ramanujan Srinivasa_ramanujan_wikipedia.ogg ipejade (Tàmil: சீனிவாச இராமானுஜன் or ஸ்ரீனிவாஸ ஐயங்கார் ராமானுஜன்) (22 December 1887 – 26 April 1920) je ara India olusemathimatiki ati akekofunraeni to, lai gba eko alagbese kankan ninu mathimatiki ogidi, ko ipa pataki si ituwo onimathimatiki, iro nomba, awon eseese alailopin ati awon ida aromoniso. Talenti Ramanujan je siso, latowo eni pataki olusemathimatiki ara Ilegeesi G.H. Hardy, pe o wa niduro kanna bi ti awon olusemathimatiki bi Euler, Gauss, Newton ati Archimedes [1].

A bi ni Erode, Tamil Nadu, India, Ramanujan koko pade mathimatiki alagbese nigba to to omo odun 10. O fi ebun re ori re han, won si fun ni awon iwe lori trigonometry agbega ti S. L. Loney ko.[2]


  1. C.P. Snow Foreword to "A Mathematician's Apology" by G.H. Hardy
  2. Berndt, Bruce C. (2001). Ramanujan: Essays and Surveys. Providence, Rhode Island: American Mathematical Society. pp. 9. ISBN 0-8218-2624-7.