100 Magias de Ogun
100 Magias de Ogun
100 Magias de Ogun
Módulo Avançado
-Módulo avanzado
AULA(33)
TRADUCCION:
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
ODU IWORI WOFUN
TRADUCCION:
ODU OGBE ATE
TRADUCCION:
AULA (36)
Eni to ba puro
Iro a pa
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
13
WHATSAPP +55 11 954785170
Eni ti o ba seke
Eke a ke won lowo
A ke wån lese
A ti won si gburugburu ona oun
Awon lo se ifa fun ajangurumale
Ti nse oluwo lode orun
Gbogbo eni ti o ba
Nfi suru pe suru
Ajangurumale ifa
Ni yoo ja won sorun
Gbogbo eni ti o ba
Nfi suru pe suru
Ajangurumale, ifa ni yoo ja won sorun
E ma fi oku pe aye
E ma fi aye pe oku
Eni ti o ba fi oku pe aye
Eni ti o ba fi aye pe oku
Ajangurumale ifa ni yoo ja won sorun
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
Ajangurumale
E ma fi abiyamo pe agan
E ma fi agan pe oyibi
Eni ti o ba fi abiyamo pe agan
Ti o fi agan pe oyibi
Ajangurumale, ifa ni yoo ja won sorun.
TRADUCCION:
ODU OFUN SE
Bí bèmbé bá ko gúdù
Gbogbo aya oba ló njó.
A d’ifá fún adabo.
Adabo nti òrun bò wá ayé.
TRADUCCION:
Cuando bèmbé
hace sonidos de tambor
Todas las reinas jovialmente bailan
¿Por qué no?
(ayuda en la manifestación del ebo)
Cuando venía del cielo a la tierra
Estamos haciendo el ebo con el dinero
Si, por favor, haga que el ebo se manifieste
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
Si los materiales para el ebo son
completos deje que se manifieste
Por favor, deje que el ebo se manifieste
para el cliente.
AULA (38)
Kó fi adá rubo
Si Òrúnmìlà
Ki Òrúnmìlà le fún
Ati àwon omo re
Agbara atí gbà emí
Gegebi etutu si Òrìsà
Ati egún
Orunmila so wí pe
Bo se wà lati atete kó se
Ti Bàbàláwo atí iyaonifá
Bà bere Ifá
Atí asé lowo ogun
Fun etutu
Àwon Orisà
Ogun rubo
ó fún Òrúnmìlà lo be
Oná sí la fún ó je pe
Àwon omo Òrúnmìlà ni
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
Yó ó sa lati iyaonifa
Ní ase
Won nkorin
Ogun fún wón ní ase
Lati odo Òrúnmìlà pe
Ti won kó ba rubo
Kó ní si ibukun
Atí alafia laye
Abowaba awo ode Orun
A d'ífá fun Orunmila
Kó ní ipin
Pelu Orunmila ko le
Dí bàbálawo atí asiri
Àwon omo Orunmila
Agbara àwon olugbe aye
Ní yó ó fún won ni
Ominira ojuse ogun ni
Pelú Orunmila náa ní
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
21
WHATSAPP +55 11 954785170
ODU OGBE DI
El día en que venía hacia la Tierra
Él dijo para ir a la casa de Òrúnmìlà
Ifá le dijo para tener éxito en su misión
Yo era y dijo que tenía el poder
Lleve la vida
Cómo castigo de OLORUN
Y como un sacrificio para Òrìsà
Él debe ser el sacrificio hecho
Antes de su partida
Y ofrecer Òrúnmìlà
SU FACA
Òrúnmìlà y
sus hijos e hijas sacerdotes
Porque recibieron la autoridad
Para quitar la vida para el sacrificio
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
23
WHATSAPP +55 11 954785170
Òrìsà
Òrúnmìlà dijo posteriormente
Bàbàláwos e iyaonífás
Se inició en Ifá
Ellos recibirán autoridad Ògún
Òrìsà sacrificio y Ògún
Ògún hizo sacrificio y entregó el cuchillo
para Òrúnmìlà
Misión fue exitosa
Para los hijos de Òrúnmìlà
Ellos cuidan de sacrificio Òrìsà
Ellos tendrán autoridad
Concesión que he convertido
Sacerdotes Òrìsà
Ellos cantaron que
RECIBIR la autoridad
Orunmila
Él les dio
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
Hijos de Òrìsà.
Òrúnmìlà media
Sin sacrificio
Fía BENDICIONES.
AULA (39)
ODU ÒTÚRÁ-RETE
Òtúrá-Rata, Tún’rárata.
Biabi’ni a tún’rá ani bi,
Òtúrá-Rata, Amuwan, Amuwan, Enima’wan
kiitä.
Emi I tani ma’wan?
þrúnmìlà I aniti næiæa.
Emi I tanima’wan?
þrúnmìlà I aniti kiina ‘wo awe ra tan.
Emi I tanima’wan?
þrúnmìlà I aniti kiija jale.
Emi I tanima’wan?
TRADUCCION:
ODU ÒTÚRÁ-RETE
Òtúrá-Rete te controla.
Si usted nace, trate de producirse de
nuevo.
Ôtúrá-Rete, Amuwon, Amuwon, él que
sabe que la moderación nunca entrará en
desgracia.
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
27
WHATSAPP +55 11 954785170
Aula (40)
TRADUCCION:
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
ODU ÒTÚRÀ ÓGBÈ
Owara-gun o riwa n mi
Beeyan lowo ti o niwa
Bi o niwa olowo ni
Iwa la n ola Iwa
Traduccion:
Alakan ni Pepepepe
Díf´fún igba Irúnmolè ojùkòtún Olórun,
A bù fún iba Irùnmolé ojùkòsi Olórun,
Ti wón bòwa ilé ayé pèlú Òsn Sèègèsí
Olóòya-iyùn,
Láti pèsè ilé ayé fún gbogbo èdá.
Nígbàtí wón dé ilé ayé, wón kò féé
Fìmó se t´Òsun.
Njé Òsun bèrè sí bé ìkòkò ba ebo Irúnmole
jé.
Gbogbo èro àti íse won sí kùnà.
Wón gbéa; wón lo òdò Olódumare.
Wón nì gbogbo ohun ti ó ní won lo se,
Wón ní kò seé se.
Olódùmarè ní: “¿Òsun, obinrin kan ti nbe
Láarín yin nkó?”
Ò ní njé, “¿e fìmò se tirè?”
Wón ní àwon ófìmò se tirè
Escola Superior de Ifá Olúwo Ifagbaiyin Agboola
Olódùmarè níkí wón lo fìmo se tirè.
Wón wá padà wá sílé ayé.
Wón wá fìmò se t´Osun
Nígbànáà gbogbo èro àti ìse
Won bèrè síí gún.
Nítorínáà, a fìmò jé t´Òsun
Yèyé wa a bá wón pé nímò.
TRADUCCION:
AULA (43)
TRADUCCION:
AULA (44)
Didun ni t'agbon
Didun ni t'oguro
Didun ni t ' ereke
TRADUCCION:
TRADUCCION:
AULA (46)
TRADUCCION:
AULA (47)
AULA( 48)
TRADUCCION: