Oriki Logun Edé
Oriki Logun Edé
Oriki Logun Edé
Okansoso
Oda di ohùn
O ko ele pé li aiya
Ajongolo Okunrin
O tó bi won ti ji re re
A ri gbamu ojiji
O je oruko bi Soponna
Oda bi odundun
Jojo bi agbo
Elewa ejela
A li bilibi ilebe
O je owú baludi
O kó koriko lehin
O kó araman lehin
Ole yo li ero
Okunrin sembeluju
A mò ona oko ko n ló
A mo ona runsun rdenreden
O duro ti olobi kò rà je
Koro bi eni lo
Oko Ahotomi
Oko Fegbejoloro
Oko Onikunoro
Oko Adapatila
O wi be se be
Sakoto abi ara fini
Tradução em português