Consagração Adje Saluga
Consagração Adje Saluga
Consagração Adje Saluga
I I I I I I I I
I I I I I I II II
I II I I I I I II II
I I I I I I I I
Odú 2
Gbe ire bo wa
Yiye ni ye eyele
Odu 3
Temi wa fun mi lo ni
1.
Ajé iwo lọbi Ògún ilu
Ajé iwo lọbi Olufa
Ajé iwo lọbi onipasan owere
Oyale asin win oso asin win dọ́lọ́wọ́
Oyale asin wẹrẹ oso asin wẹrẹ di aniyan-pataki
Ajé pè lẹ ó a kín l’Òrìṣàs
Agẹ́ dẹ́ ní wò Ajénjé lotu Ifé ti ó fi njọ kóo tí ní
Ajé dakun wà jọ́ kóo tẹ̀mi kí ó má ṣe kuro lọdọ mi
2.
Ajé pèlé oní ṣọ
Ajé ti n ṣọ ewé dá gbà
Agbẹ̀bí ọ̀rọ̀ kó rò ọdẹ rò
Ogẹ̀dẹ̀ lajé njẹ́ lọ tu Ifé ti fi njó kó
Ó tẹ̀mi
Ajé dákun wà jó kó ò tẹ̀mi
Èyí ti kó sí nu tọmọ aráyé ò máà
Wà kí rí
Ajé máà bò lọ domi èmi
Oní le kan dá ṣe le ayé
Akéhin l’Òrìṣà
Ajé eu te saúdo
Você é a única que fica onde quiser
A que faz os menores serem respeitados
Como pessoas maiores
A que facilita as coisas
A que come banana em Ifé para ficar com uma
Ajé por favor venha ficar comigo
A que não se perde e busca as pessoas
Venha a mim, eu não posso viver sozinho. O último Òrìṣà que veio.
3.
Tradução
Sikiti é o que chamamos Ajé
Sikiti é o que responde ao chamado de Odùduwá
Sikiti desaba em meus pés
Olókun me abençoa com muita riqueza
Amukeke é a mãe que deu a luz a Olókun
Aqueles que comemìrókòcasca comìrókò
Aqueles que comemas nozes sãocomo nozes
Depois decomer eficarsatisfeito
Disseram ObaraKa impressiona
MasObaraKa não impressionar
O dia que Obara visitou a casa de Ìká
Foi quando a casa se encheu de riqueza em abundancia
Minha pombavoouatravés do oceano
Paratrazer sorte edinheiro,
Mas com muita abundância.
4.
Aje o labokun
Aje o labokun
Aje o labokun
Osi rabu rabu o lebeka
Senisa ni yeye aje
Asa leyo leyo
Arin leyo leyo
Ona gboro lobaje
Iya Aje wa joko kale Si le awa
Eda giri omo e ma wo Towon bo
Tani o tare tawa wa funwa
Aguntan Ifa ni o tare
Tawa wa fun wa aguntan
5.
Aje Oguguloso
A to po lowo awure
Aje o
Je nri e mu na
Je nri e mu lo
Ela iwori
Aje je nri e na dajo ale
6.
Aje o ! Ogunguniso
Aje o !! Ogunguniso
Aje o !!! Ogunguniso
Aje mo un pe o wa da milohun Je ka jo ma gbe
Aje duro demi ma lo sibikankan
Iberu oluwa ni ipinlese ogbon
Iberu oluwa ni ipinlese ogbon
Talika to yan oloro lodi
Yeye ara e lomi se o
Tradução:
Ose 02
Osa w pé k a lo bo Osun
Nibi ti a gba ri agbagba marun
Osa pé ire omo ni on fo
O ri ona t Osa gba
T o fi je be
Ina ji ina a gb ewu oseriseri b orun
Osupa ji a gb awo yinyin
Da fun ya mi Otolo Efon
Osun fun mi ti e s ogbere omo.
Nwon ni ki nOsun o ru bo
Kil on a ru
Nwon ni o r egba mar um
Nwon ni o r’akuko adie
Nwon ni o r’agbebio adie
Nwon ni o ru opolopo yanrin
Nwon ni ki Osun o ru ide
Osun as k’ebo o ru bo nu
O k’eru o tu
Be nu Osun bere si omo bi
K’Osun o ma bi mo baun
Ile’e kun ona e gba
Osun ni w anjo ni nyo