Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Òkun Arábíà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Arabian Sea)
Òkun Arábíà
Arabian Sea
Coordinates 15°55′10″N 63°54′22″E / 15.91944°N 63.90611°E / 15.91944; 63.90611Coordinates: 15°55′10″N 63°54′22″E / 15.91944°N 63.90611°E / 15.91944; 63.90611
Max. width 2,400 km (1,500 mi)
Surface area 3,862,000 km2 (1,491,000 sq mi)
Max. depth 4,652 m (15,262 ft)

Okun Arabia (Sanskrit: सिन्धु सागर, pipe: Sindhu Sagar; Lárúbáwá: بحر العرب‎, pipe: Baḥr al-'Arab; Marathi: अरबी समुद्र, pipe: Arabi samudra; Malayalam: അറബിക്കടൽ, pipe: Aṟabikkaṭal) je ara Okun India to jamo India ni ilaorun, ni ariwa mo Pakistan ati Iran, ni iwoorun mo Erekusuile Arabia, ni guusu, ni die, mo ila larin Cape Guardafui, ojuile ariwa-ilaorun Somalia, Socotra, ati Kanyakumari (Cape Comorin) ni India.