Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Augustus

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gaius Julius Caesar Augustus
Emperor of the Roman Empire

Laureate bust of Augustus
Reign 16 January 27 BC – 19 August AD 14
Successor Tiberius
Spouse 1) Clodia Pulchra 43–40 BC
2) Scribonia 40–38 BC
3) Livia Drusilla 38 BC–AD 14
Issue
Julia the Elder;
Gaius Caesar (adoptive);
Lucius Caesar (adoptive);
Tiberius (adoptive)
Full name
Gaius Octavius Thurinus (from birth to adoption by Julius Caesar in 44 BC);
Gaius Julius Caesar (from 44 to 27 BC);
Gaius Julius Caesar Augustus (from 27 BC until death)
Father Natural: Gaius Octavius;
Adoptive: Julius Caesar (In 44 BC)
Mother Atia Balba Caesonia
Burial Mausoleum of Augustus, Rome
These articles cover Ancient Rome and the fall of the Republic
Roman Republic, Mark Antony, Cleopatra VII, Assassination of Julius Caesar, Pompey, Theatre of Pompey, Cicero, First Triumvirate

Gaius Julius Caesar Augustus (23 September 63 BC – 19 August AD 14) ni olori akoko Ile Obaluaye Romu, to jaba le lori lati January 27 kJ titi di ojo iku re ni 14 lJ.[note 1] Bibi gege bi Gaius Octavius Thurinus, o je gbigba bi omo posthumously latowo egbon-baba-baba re Gaius Julius Caesar leyin igba to ku ni 44 kJ, be sini larin igba na ati 31 kJ oruko re fun tonibise je Gaius Julius Caesar. Ni 27 kJ Ile Alagba fun ni ebun oye oniyi Augustus ("ẹni ọ̀wọ̀"; "the revered one"), leyin igbana oruko re di Gaius Julius Caesar Augustus.[note 2] Nitori opolopo oruko ti a mo si, o wopo lati pe ni Octavius ti a ba n toka si awon isele larin odun 63kJ ati 44 kJ, Octavian (tabi Octavianus) ti a ba n toka si awon isele larin odun 44 kJ ati 27 kJ, ati bi Augustus ti a ba n toka si awon isele leyin 27 kJ. Ninu awon iwe ti orisun won wa lati ede Griiki, Augustus je mimo bi Ὀκτάβιος (Octavius), Καῖσαρ (Caesar; Kesari), Αὔγουστος (Augustus), tabi Σεβαστός (Sebastos), lori ba ba se ni ibamu si.




  1. The dates of his rule are contemporary dates; Augustus lived under two calendars, the Roman Republican until 45 BC, and the Julian after 45 BC. Due to departures from Julius Caesar's intentions, Augustus restored the Julian calendar in 8 BC, and the correspondence between the proleptic Julian calendar and the actual calendar observed in Rome is uncertain before 8 BC.(Blackburn & Holford-Strevens 2003: 670–1)
  2. Formally Imperator Caesar, Divi filius, Augustus which means Imperator Caesar, Son of the Divus (Divus Julius), Augustus.