Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Baruch Spinoza

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Baruch de Spinoza
OrúkọBaruch de Spinoza
Ìbí(1632-11-24)Oṣù Kọkànlá 24, 1632
Amsterdam, Dutch Republic
AláìsíFebruary 21, 1677(1677-02-21) (ọmọ ọdún 44)
The Hague, Dutch Republic
Ìgbà17th-century philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Rationalism, founder of Spinozism
Ìjẹlógún ganganEthics, Epistemology, Metaphysics
Àròwá pàtàkìPanentheism, Pantheism, Determinism, Deism, neutral monism, intellectual and religious freedom / separation of church and state, Criticism of Mosaic authorship of some books of the Hebrew Bible, Political society derived from power, not contract

Baruch Spinoza (Hébérù: ברוך שפינוזהBaruch Shpinoza, Pọrtugí: Bento de Espinosa, Látìnì: Benedictus de Spinoza) to di Benedict Spinoza (November 24, 1632 – February 21, 1677) je omo Portogi ara Hollandi elesin Ju amoye.[1] Pelu opolo onisayensi to ni, bi ise Spinoza se lagbara to ati se pataki to ko han titi ki o to ku. Loni, o je gbigba bi ikan ninu awon aselaakaye olokiki[2] imoye orundun 17k, to se ipilese fun Olaju orundun 18k[2] ati iseagbewo bibeli odeoni.[2] Nitori iwe re Ethics, to jade leyin iku re, ninu ibi to ti lodi si iseonimeji okan-ara Descartes, Spinoza je gbigba bi ikan ninu awon amoye pataki ninu Imooye apaiwoorun. Amoye ati akoitan Georg Wilhelm Friedrich Hegel so nipa gbogbo awon amoye igbalode pe, "E le je Asespinosa tabi ki e mo je amoye rara."[3]


  1. 1.0 1.1 1.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named tws908
  2. 2.0 2.1 2.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named tws9909
  3. Hegel's History of Philosophy