Iba Oo
Iba Oo
Iba Oo
Ose Otua iwo loo saaju ebo , Iwo loo sii kanyin
ebo
To ni Oluwo
Tufee ni Odugbona
Oro kan
Oro Kan
Eyi ti Babalawo b aso sile a degub lailai
Ase ale ase oworo
A d fn argb abor kokooko
Nijo ti n lo ree ba won naja ojugboromekun
Won larugbo oloso
O oloun loso
Won larugboo lajee
O loun o lajee
O nin sugbon oun lafose lenu
Nje eni t oba sun ko d ide
Igba Akuko n daja
Eni o ba sun ko d ide
2. wnrn ajise (wnrn br)
Otun awo Aba
Oun lo sefa fun won lode Aba
Sawarepepe
Epe moo belepe lo o
Nijo tewure ba boju weyin nii fepe felepe
Sawarepepe
Epe moo belepe o
Sawarepepe.
Iwure: Ifa dakun Orunmila dabo! Bi eni to dafa
yii b alo sajo, je ko dele layo lalaafia ma
Iwure : Ki egun elegun epe elep o mo lee um
lagbaja yii o.
Ose Otura(2)
Bolu b alo! Olu nii sin in Osetura waa ba ni
lase si elo yii
Atepo
Arepo
Awon me jeeji ni won jojo faakara n uwo
A d ifa fun f ejerindilogun orodo
Eji Ogbe
Eji Ogbe dakun dabo fiye denu koo fiye dekun
A kii Gboju ka f oloja jeri ejo
Ifa laa mo o f oloja jeri ejo
Sugbon iro laa gbodo p amo on
Agunmonna Awo eba ona
Oun lo d Ifa fun seboosoosa
Okaran Meji
Okaran Meji , ebo yii ti di eboo re koo bani se
dandan koo segun awon otaa re
Okanran kan nihiin
Okanran kan lohuun
Okanran me jeeji a bidi jogodo
A d ifa fun Oya ti n sunkun omo rele onira
Ebo lo se ko too lo
Owonrin S Ogbe
Esu peere jegede!
Egba peere jegede!
A d Ifa fun Ologeeesa
Eyi ti o koro leje tomotomo
Ebo araye ni won ni ko waa se
Eje awa koro awa o ku mo
A dewee j ogbo
Eje awa momo koro
Iwure: Ifa je ki eje lagbaja koro lenu oso lenu
aje lenu eleboloogun
Obara B Ogbe
Obara B Ogbe ! ebo yii di tire, koo je k ebo o
fin ki eru o da ko dode orun ko se si toloore
Itan Ega o see salejo
A d ifa fun Ajankoorodugbe
Eyi ti n sawo rele Elewii
Awa rubo
Eboda na o
A momo s ebo ajankoorodugbe Ifa wa se
Iwure : Ifa je ki ebo yii fin koo je ko da ko
dode orun ko se si tolore
(2)
A bu si tun yin
A dia fu nojo
Ojo tii o sai tun fi yin in leyinwa
Nje a bu si tun yin
Ojo loko agbado
A bu si tun yin
15 Ogundabede (1)
Ogundabede, iwo loo da ebo ni Igara ti o kii je ki
ebo o fin
Iwo loo da etutu ni Igara ti kii fii gba won ni iru ebo
won ni??
Oni ebo ti won o ba ti pe o si ni, a pe o si ebo (nome
of odu casted in divination) ni koo dabo ki o ba ni
gbe ebo yii lo si ode orun, ko fin ko da, a fowo omo
kekere ruu, ki o waa fowo agbalagba agbaa
Eniyan ti ko lowo lowo
Ogundabede (2)
Bd
Awo won lode Ipo
Awe
Awo ode Ijesa
Ominrinminrin ara iramori
Igi ganganran mose gun mi loje
Olorun d ebiti oran kale
A kii ralawo si rejereje
Awon lo dia fun Olofin
Nijo ti won k ebo keedi ti oun
Oseroyin (2)
Bomode ba mosee je
Won a jonize
Bi won o si moo e
Won a je Oluse
Ise lawa ti n je f oba awa lailai
A d ia fun Oba oropo iyun eyi ti n lo ree jise ola
feebo
Nje jeere o
Ose Pawori
Jeere o
Bo ba dele koo jise owo
Ose Otura(3)
Osetura pele oo! Awurela Akinnoso! Bo oba saaju
ebo si kanhin ebo
Ose ni won n peja nile alake
Okiribojo lomi Ilawe
Bojo ba ro lodi l eso
Eja gborogboro a maa lorun bo waye
Ope a bifo jinginni
A d ifa fun won n ile Ilose
A bu tun won n ile Ejigan
Won n won o rubo ki won o lee lowo n ile Ilose
Won n won o rubo ki won o lee bimo lemo n ile
Ejigan
Awon mejeeji lo rubo
Ilose laa pe Ijebu
Ejigan laa pe Ile-Ife oodaye
Orunmila je ki lamonrin lowo bi ara Ilose laye
OseOtura (4)
Ose Otura gba a tete
Ajikansee lekun
A dia fun akilolo ti n gbegbo r ode orun
A pe emi ni mo mo mo mo ko ko ko debi yii
Ebo toun ni ko te te te te te da
Ebo toun ni ko te te te te te fin
Riru ebo eeru atu Esu
Aye ye wa tuturu
Ou
Ose Otura bba a tete
Ajikansee lekun
Imoran mefa
Oran ti won mo moo mo
Ti won o leem o tan
N ni won n difaa si
A dia fun Olu
Nijo ti n gboguun lo ilu gbendu gbendu
Esin gagaagan nwaju olu
Oko gagaagan leyin re
Ogun ti won fesin foko j
Eyi ti won o lee se
Iruke bayii n ifa fii tumoo re
( the babalawo would use his right hand or rkre
(cow tail) to fan the top of the sacrifice)
Tumo iku fun-um
Tumo arun fun-um
Tumo Ofo fun-um
Tumo gbogbo ajogun fun-um
Iwure : Ifa ti lamonrin ba lo si egbe je ko dele layo
lalaafia. Ifa ma je ko ri idana aburu .
1.After the Iyerosun of Okanran Osa is sprinkled on
the sacrifice, chant the following the prayer.
Iwure: Emeta laa k Eruku f Oloja
(its is three times that we give Eruku to Oloja)
Efon di o um o yanjana.
Agbanrere di o um o l awo l ori sanransanran
A dia fun waagbani tiii s omo Olopa ororo
O f eegun ile segbeje
O f oosa ibe segbefa
O ni kaka k oun o ti waa yan Edu um ope di o um
Koo mo yin mi nu
Iyere ara igi nii won
Tara ope kii won danu
Eniyan kii as go r ope kiku o ji
Oluwaa rep a!
Iwure:
Nijo l iku n bo, k ifa o bo o
Nijo arun n bo, k ifa o bo o
Nijo ofo n bo, k ifa o bo o
Nijo ija n bo, k ifa o bo o
Nijo ese n bo, k ifa o bo o
Nijo egba n bo, k ifa o bo o
Nijo gbogbo ajogun n bo o bo o
Sugbon nijo t ire aje, ire aya, pipe l aye, gbogbo ire
ba de k ifa o si o s ile.