Location via proxy:   [ UP ]  
[Report a bug]   [Manage cookies]                
Jump to content

Anguidae

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Anguidae
Temporal range: Late Cretaceous to present
Anguis fragilis
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Infraorder:
Ìdílé:
Anguidae
Genera

Anguis
Ophisaurus (glass lizards)
Pseudopus
Celestus
Diploglossus
Dopasia[1]
Ophiodes
Abronia
Barisia
Coloptychon
Elgaria
Gerrhonotus
Mesaspis

Anguidae jẹ́ orúkọ àwọn ẹbí tí ó tóbi tí ó jẹ́ ti aláǹgbá ti Northern Hemisphere. Àwọn tí ó wà ní ẹgbẹ́ yìí ni àwọn slowworm, alángbá gílásì àti alángbá inú omi, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. Wọ́n pín ẹbí yìí sí àwọn ẹbí mẹ́ta tí ó sì ní àwọn ẹ̀yà mẹ́rìnlé làádọ́rún ní àwọn ìdílé mẹjọ. Wọ́n ní àwọn osteodem tó le ní abẹ́ awọ ara wọn àti pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwpọn èyà yí ní àwọn ọwọ́ kúkurú tàbí tí kò sí rárá, léyí tí ó jẹ́ kí wọ́n dàbí ejò bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn òmíràn ní ọwọ́ tó pé.[2]

Helodermoides tuberculatus fossil
  •   Ìbátan ẹbí Anguinae
    •   Ìdílé Anguis - arọ̀n kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ (àwọn ẹ̀yà méjì)
    •   ÌdíléDopasia - Àwọn alangbá gílásì ti Asia (àwọn ẹ̀yà mẹ́fà)
    •   Ìdílé Hyalosaurus - Àríwá alangbá gílásì ti Àríwá Africa ( ẹ̀yà kan)
    • Genus Ophisaurus - Àwọn alangbá gílásì ti Amẹ́ríkà  (àwọn ẹ̀yà marún)
    •   Ìdílé Pseudopus - scheltopusik (ẹ̀yà kan)
  •   Ìbátan ẹbí Diploglossinae
    •   Ìdílé Celestus - galliwasps (A\wọn ẹ̀yà márùnlélọ́gbọ̀n)
    •   Ìdílé Diploglossus - galliwasps (àwọn ẹ̀yà ọ̀kàndínlógún)
    •   Ìdílé Ophiodes - (àwọn ẹ̀yà mẹ́rin)
  •   Ìbátan ẹbí Gerrhonotinae - àwọn alangbá inú omi
    •   Ìdílé Gerrhonotus (àwọn ẹ̀yà mẹ́rin) - àwọn alangbá inú omi
    •   Ìdílé Abronia (27 species) - àwọn alángbá tí ó n gbé orí ilẹ̀ àti orí igi

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. * Nguyen, T.Q. et al. 2011: Review of the genus Dopasia Gray, 1853 (Squamata: Anguidae) in the Indochina subregion. ISSN 1175-5326 Zootaxa, 2894: 58–68. Preview
  2. Bauer, Aaron M. (1998). Encyclopedia of Reptiles and Amphibians. San Diego: Academic Press. pp. 152–155. ISBN 0-12-178560-2.