Orin Àgbónnìrègún
Orin Àgbónnìrègún
Orin Àgbónnìrègún
Mo júbà Àgbónnìrègún
Mo júbà Àgbónnìrègún
Àwa pàdé l’ònòn ipòrùn, ipòrùn
Wa pàdé l’ònòn ipòrùn, ipòrun
Àwa mésòn òrun korin kí Òrúnmìlà
Àwa tún wo tún wà korin kí Òrúnmìlà
Àwa orí ofe, ofe Edùmarè!
Àwa orí ofe, ofe Edùmarè!